Oríṣun àwòrán, Taooma/Facebook/Brain Jotter/Facebook/Farooq Oreagba/Instagram Ọdun 2024 jẹ ọdun kan t'awọn ọmọ Naijiria da awọn aṣa kan eyi to di ohun tawọn eeyan n sọ ...
Iṣe aago titunṣe ni Bala Muhammad n ṣe niluu Kaduna, ni Naijiria. Ti ẹ ba wọ inu ṣọọbu rẹ, oniruru aago atijọ ati aago aye ode oni ni ẹ maa ba ninu ṣọọbu naa. Ọkan ...