In the heart of Ibadan, where history and culture intertwine, the Ose Meji Festival stands as a sacred ritual, deeply rooted in the city’s founding legend. This festival honours Lagelu, the progenitor ...
Inu ibanujẹ ni mọlẹbi Onuche wa bayii, pẹlu bi wọn ṣe n ṣọfọ awọn ọmọ wọn obinrin meji, ti awọn afurasi eletutu ọla pa nipakupa niluu Port Harcourt, nipinlẹ Rivers.
"Awọn meji yooku, Charlse Mkpang pẹlu eeyan mii ni wọn wa ni ile iwosan nibi ti wọn ti n gba itọju." Ileeṣẹ ọlọpaa ni Bassey ni o ti w ani ahamọ bayii, ti iwadii si ti ...